Tuesday, 27 January 2015

Ileri Oluwa lyrics

CHORUS: Ileri re layemi kooma niye oo
e. Ileri re layemi koma niye oo Pebi giga
to gaju le ngbemi lo oo e. pepele tokan
layemi ti igbega ni oo. Ileri oluwa o
awasimuse dandan.

LEAD: Ileri ti e se, nipe agan adolomo.
Wipe koni si agan ni ileyi mo, rojo ibukun
sinu ilee wa, rojo ibukun sori isee wa,
rojo ibukun re, sorile ede yi o. Kirugbin
ashale, kole so eso rere jade!
ee,ee,ee,ee.

Chorus....

Call. Awon onise owo o baba.. Resp.
Jeki won maa rise.. Gbogbo onise osu
baba mimo Resp. Wa fun won ni
igbega... Call: majemu te bawa daaa
Resp: Jeko wa si imuse..
Lead: Ileri te se fun mi oo baba, nipe e o
so agbegbe mi di nla o. Baba, jeki jobaa
re de saye mi. Jeki jobaa re de sinu
isemi. kemi rona gbegba ooo
Resp: Tete wa bamide... Lead: Eyin sa
lese Tobediodomu oo... Taye tiro pe oti
pari fun oo. Joseph bi ogun ti pofun too.

Resp. E sodi prime minister Lead. Aye
febami gbegba ope won nreti ibukun re
layemi ooo. Asiko mi ti tooo baba mimo.
Igba sa lonigba nloo. ee! maje ntawona
maje ntaraka, gbogbo ijakule mi... waa
f'opin si.
ALL.
Ileri tese funmi oo baba 3x Longtime ayo
mi, tete wa muse.

No comments:

Post a Comment